Fun awon elere ti won n gbe igbe aye gidi pelu awon afojusunto gba ti e
Fun awon elere ti won n gbe igbe aye gidi pelu awon afojusun to gba ti e
A n so pọ mọ aago tabi ohun elo ara re, awon app ilera re, ati igbe aye re gidi lati ko eto ikoni to boju mu fun oni, kii se eto ti a ti ko sile lati opolopo ose seyin.

Yi lo si isale lati wo siwaju
01 // Kini Imperfect
Ikoni n tesiwaju
Kii se oro kiki titepele mo eto lai foju si i mo. Imperfect n sopo pelu data ilera re yala o n sare, o n gun keke, o n we, tabi o n gun oke. Bi ojo se n lo, o n gba awon imoran to ba bi o se n gbe aye re mu gangan.
Awon afojusun re, igbese re
Eto re n ba o rin. Agbara re, eto ojo re, aye re. Ko si idi lati fi agidi mo eto to le koko.
Ara re n soro. A n gbo
Lojo miiran, o ma ti kankan. Lojo miiran, o ma sinmi. A n satunse ki o le ma ba a lo.
Gbogbo igbese lo se pataki
O fo ojo kan? O wa lara e. Pada wa lola.
02 // Bi o se n sise
Bí ayé rẹ ṣe ń lọ la ṣe ń tèlé e
A wà lẹ́yìn rẹ
A máa ń ṣètò lójú ẹsẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ọjọ́ rẹ àti ohun tó ń ṣẹlẹ̀ ní àyíká rẹ ṣe rí.

Afẹ́fẹ́ àyíká · kò dára tó
Jẹ́ ká lọ sáré nínú ilé
Eré orí Treadmill · 5K
03 // Àwọn eré ìdárayá
A kọ́ ọ fún bí o ṣe ń gbégbésẹ̀
Láti orí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ ojoojúmọ́ dé orí àwọn eré àkànṣe. A ń kọ́ ọ pẹ̀lú àwọn eléré, a sì ń fẹ̀ ẹ́ síwájú pẹ̀lú rẹ.

A ṣe é fún bí o ṣe ń gbéra

FAQ




